Sebi wọn ẹkọnomi wá kò dára ní? Maamu kan tó jẹ́ ajeseku lo tí setan báyìí láti ṣe ìgbéyàwó fún obìnrin méjì lọ́jọ́ kan naa ni ìpínlè Abia ...
Read More
Home / Iroyin Kayeefi
Showing posts with label Iroyin Kayeefi. Show all posts
Showing posts with label Iroyin Kayeefi. Show all posts
Ẹ wá wo ohun tí wọn ni kọ seese
Kini wọn ni kó seese nínú ayé rẹ? Kini ohun tó mú ọ sọ ìrètí nù? Edumare yóò mú ọ pàdé ìyanu rẹ lọjọ kan. Má sọ ìrètí nù!
Read More
Àṣírí ọmọ odò tu: Ogun abẹnu gọngọ ni wọn ká mọ ọ lọ́wọ́
Àṣírí ọmọ odò tu: Ogun abẹnu gọngọ ni wọn ká mọ ọ lọ́wọ́ lẹ́yìn ọjọ́ kẹta tó bẹ̀rẹ̀ ìṣe
Read More
"Osu Keje ọdún ló yẹ kí n bímọ ṣùgbọ́n oṣù kẹrin lọ wà saye" - Ìyá Iyanu
"Ona ara jí Ọlọ́run gbà jomiloju. Mo bí ọmọ nínú oṣù kẹrin ọdún 2017 ṣùgbọ́n oṣù keje gan-an ló yẹ kó wáyé. Ọkàn mi kò sókè, ó sì dabi ...
Read More
OMO ỌDÚN MOKANLA (11YRS) TÍ LÓYÚN OṢÙ MÁRÙN-ÚN NÍLÙÚ CHINA (2)
Ṣáájú, a ti gbé ìròyìn ọmọbìnrin ẹni ọdún mokanla tí bàbá ẹni àádọ́ta (50) fún lóyún nílùú China. Àwọn òbí ọmọ náà tí ń gbìyànjú láti ṣe o...
Read More
Omo ọdún mokanla (11yrs) tí lóyún oṣù márùn-ún nílùú China
Ọmọbìnrin ọmọ ọdún mokanla, omo ile ìwé ìlú China lọ tí lóyún oṣù márùn-ún báyìí látàrí ibasun láti ọwọ ogbeni Liu Baoming (50yrs) to je aṣó...
Read More
Wọn dinwo bebi onike fún ibalopo sì 750 000
Wọn tí dinwo bebi eléyìí wálẹ̀ sì 750, 000. Ó sì wá lórí ìgbà fún àwọn ọkùnrin tó bá nifẹ si
Read More
Wọn so tọkọtaya pọ pẹ̀lókùn ni ṣọ́ọ̀ṣì
Wọn ni kì ìgbéyàwó wọn lé wa títí láéláé ni wó ṣe ṣe bẹ́ẹ̀
Read More
Kayeefi! Won ti bere odun awon oku niluu Indonesia
Odun awon oku je odun kan pataki ti awon eya Torajan ti won wa ni Guusu Sulawesi ni orileede Indonesia maa n se. Odun yii je odun ka...
Read More
Owusu pada iku ojiji lojo odun ileya
Omokunrin kan lo ti koja lo sorun niluu Ghana nibi oun ati awon ore re ti n se faaji odun ileya to koja. Alaye oro ni yii lati owo Ci...
Read More
Abiyamo gbe ibi omo (placenta) kana
Airin jina lai ri abuke okere; ti eniyan ba rin titi yoo ri ibi ti won ti n fodo ibile jeun. Ohun ara to tun seyo lori ayelujara ni...
Read More
Aye Akamara: Leyin 21yrs to ti n wa omo, odun meta lo tun fi ru oyun akobi re
Eniyan to ba ni ko saye, won ti "sample" e ri ni. Errk. Gege bi Olanrewaju Adepoju se so ninu ewi re, oni eni aye ba da...
Read More
Opin aye ti de: Awon obirin meji ti won fe ara won ti bo si gbangba
Awon obirin meji yi, Parpistud ati Lawrencia Aligasi ti won gbe ni ilu Warri la gbo wi pe won jo fe ara won bi tokotaya. Oju ko ...
Read More
Foto obirin ti won ge ori re ni Badagry ni yii
Arabirin yii ni ogbeni Taofik ti inagije re n je Kie-Kie seku pa ni agbegbe Badagry to wa niluu Eko lojo Aiku to koja(19:03:17) ...
Read More
Okunrin ti won ka ori eniyan mo lowo ti jewo bayii
Odaju laye, gbogbo ona si awon eniyan fi n wa owo ojiji. Omokunrin ti won ka ori eniyan mo lowo ni agbegbe Badagry to wa ni ipinle Eko l...
Read More
Won ti ri oku okunrin to ko sinu omi lEko Ambode
Okunrin dokita ti won pe oruko re ni Allwell Orji, eleyii to be sinu omi lati ori afara 3rd mainland to wa niluu Eko, ni won ti ri oku...
Read More
Won ri oku ibeji ninu koto nla ni ilu Eko
Oladeji Kehinde Nibi ti awon kan ti n sunkun airomobi ni odaju abiyamo kan ti gbe awon ibeji re junu si inu koto giriwo kan ni agbeg...
Read More
Kayeefi! E wa wo ohun to sele si oku odun kerinla
Gegeg bi alaye ti a gbo, ise oju ona ti won se lo ni agbegbe epe niilo fun ki won wo awon ibi kan, eleyii ti won sin oku obirin kan si. ...
Read More
Aye Akamara: Kini won fe fi omo ti won so mole se ni Sango ota?
Omokunrin ti oruko re n je, Taiwo Korede, ni won ri nunu igbekun ijo Celestial Church of Christ (Key of Joy Parish, Ajiwo) to wa ni ...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)